GOSPEL-YORUBA

INFINITYAYE OLE

Omo eniyan feti si mi
Oro agba bi o se lowuro ase lojo ale

Bo wu kope titi iya wa
Nbo wa dopin
Ai mo la eda lo mu eda sa ni
Yan ola
Okorun ti she ileri oro baba ko ye
Al nigbagbo lo mu eda ra ro pin

Bi okun nfo ti osa sa otitio wa laaye
Igbagbo ni orison oun gbagbo

Chorus: Ohum hun aye yi ko ma le
Resp.       Aye ole fieni to je luwa le
                Foju   re woe

Abi iku ti da bi ye ninu aye mi

Oni sanu ape ko to je koni je ba je
Ai ma ni suru lo mu arin eni bwa de bi
Fo ju re womi ore ko luwa le fo ju re won abi iku ti do bi ye ninu aye mi

Aaah aye re ko ma ni ni le
Aaah boba bo  okorun rin oso ri re
Bo wu kope titi iya aye wa
Oun bowa dopin


 LARA GEORGE IJOBA ORUN

Uhuh Uhuh
Ijoba orun
Ere onigbagbo o
Ijoba urun
Ere onigbagbo o

Ma je n kuna
Baba
Mu mi dele o
Ma je n kuna
Baba se
Mu mi dele o

Owo ti mo ni
Ko le mu me de o
Mosu ti mo re ra
Ko le wa mi dele o
Gbogbo iwe timo rika
Won o le gbe mi dele o
Ma je n kuna
Baba
Mu mi dele o
Ki ma ku sajo
Bi ye fi
Mu mi dele o
Aye loja
Orun ni le

Mu mi dele o
Aye loja
Ni orun ni ile se
Mu mi dele o

Chorus: Mu mi dele o) x8
Response: mumi
Baba aye loja
Baba ooo baba ooo
Mu mi dele o

Repeat chorus
Ille ogo
Ille ayo, ille ayo
Ille alafifa 2x
Ijoba orun
Ere onigbagbo
Ma je n kuna



 INFINITYOLORI OKO
     
MMM, I have seen the future
Though am not a prophet
In the book of revelation
There’s warning for the nation
He that has an ear let him hear
What the spirit is saying

Refrain:
Ai sinle Ologbo
Lon mu eku shako (shako) 3x
Yiyo ekun nyo
Ki ma ishe tojo
Agba ki wa loja
Ko ri omo tun tun wa
Fitila yin tan (to ntan)
Imole wole wa (imole tide)

Chorus:
Olori oko si nbo wa
O nbo wa, o nbo wele 2x

Afo pinna to loun o pa fitila
Ara re ni o pa
She bi aro to bag bon eeeh
Oun longun asotefe ipa
Afo judi omo eniyan
Olorun oba iku lon mu dani

Repeat refrain and chorus

Chant:
 Olori oko nba o
Jagun molu nbo o
Papa nla tin jo
Tawn tawn, efufu
tin mile titi
Olori oko nba o,
Emura, oba a a saya
Oba adidigbo lo
Eni o di gbo lu o asi
Run womu womu